z-logo
open-access-imgOpen Access
Wútùwútù Yáákí
Author(s) -
Ọlábíyi Babalọlá Yáì
Publication year - 2021
Publication title -
yoruba studies review /yoruba studies review
Language(s) - Spanish
Resource type - Journals
eISSN - 2578-692X
pISSN - 2473-4713
DOI - 10.32473/ysr.v6i1.130107
Subject(s) - physics , chemistry
Wútùwútù yáákí; Wútùwútù yám̀bèlé; Ká súré pátápirá, Ká fè wù àlàárì fọnkun àmódi; ̣ Ẹsẹ Ifá yìí jé ọ ̀ kan nínú àwọn ifá ńláńlá tí a fà yọ kúrò nínú Òtúá Méjì. Méjì ̣ ni àwọn onímò -èdè Yorùbá tó ti yẹ ẹsẹ Ifá wò fínífíní pe ̣ ̀ lú ìjìnle ̣ ̀ ìmọ̀ òde òní ̣ nípa èdè tí a ń pè ní lìǹgúísítíkì. Ẹni àkó kọ ́ , Ọ ̀gbe ̣ ́ ni ’Wáǹdé Abímbo ̣ ́ lá la ẹsẹ ̣ Ifá sí ò nà me ̣ ́ jọ.4 Ọlátúndé Ọlátúnjí ni ẹnì kejì; òun pín ẹsẹ Ifá sí ìsò rí méje.5 Gé gẹ ́ bí a ó ṣe rí i ní ìsàle ̣ ̀ (ẹ wo àlàyé 2), àwọn àye ̣ ̀ wò méjèèjì tí a dárúkọ ̣ wò nyí pọwo ̣ ̣ ́ léra. Nínú àdìtú wa yìí, ètò ẹsẹ Ifá onídàáméje ni a ó mùú lò nítorí pé ó dà bí ẹní bá ẹsẹ Ifá yìí mu jù lọ. Nínú ìdá èkìíní (Ìlà 1 dé 8), a lè pín àwọn gbólóhùn ibè sí oríṣìí meta.

The content you want is available to Zendy users.

Already have an account? Click here to sign in.
Having issues? You can contact us here